Wednesday, March 27, 2013

OrikiORIKI

Part 1:
Ka-biyesi  atoperi Eledumare mi se
Ka-biyesi  agba nla atoperi Eledumare mi se
Baba mi awimayehun, Baba mi awilese
Baba mi aselewi, Baba mi, Baba nla ti ngbani
Gbani Gbani lojo isoro, eleti gbohun gbaroye
Afetilukara bi ajere , eru jeje leti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni, Ota somo bi eni taso
Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai

Part 2:
Eyin loba to nse oun gbogbo lodu
Eyin lakoda, eyin laseda, eyin laweda
Eyin lameda, ogbagba tirin gbagba
Alagbada ina, alawotele oorun
Alade gbedegbede bi eni n layin
Edumare moti mope mi wa feni tope ye fun
Moti fiyin feni tiyin se tire o

Part3:
Eni to n se mimo, to n je mimo, to n mu mimo
To n gbe bi mimo, to niwa mimo, Alade ogo
Talaba fi o we , na you bi ano, na you bi oni
Na u tuni lola, ope ye o o Baba, Edumare gbope wa

 Tire ni o, tire ni o
Mo fi sile fun o (repeat)
Females: Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa
(Modulation)
Tire ni o/7x
(Modulation)
Tire ni o/7x
(Modulation)
Call- my praise
Resp: my praise
Call- Belongs to you
Resp: Belongs to you
Call: Ese
Resp: Ese
Call: Adupe o
Resp: Adupe o
Call: Igwe/6x (nna naba me)
Resp: Igwe

No comments:

Post a Comment